Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhábù sì wí fún Nábótì pé, “Fún mi ní ọgbà àjàrà rẹ, kí èmi kí ó fi ṣe ọgbà-ewébẹ̀, nítorí tí ó súnmọ́ tòsí ilé mi; Èmi yóò sì fún ọ ní ọgbà àjàrà tí ó sàn jù ú lọ dípò rẹ̀; tàbí bí ó bá sì dára ní ojú rẹ, èmi yóò fi iye owó rẹ̀ fún ọ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:2 ni o tọ