Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Jésébélì sì ti gbọ́ pé, a ti sọ Nábótì ní Òkúta pa, ó sì wí fún Áhábù pé, “Dìde! Kí o sì jogún ọgbà àjàrà Nábótì, ará Jésérẹ́lì, tí ó kọ̀ láti tà fún ọ kò sí láàyè mọ́, ó ti kú.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:15 ni o tọ