Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 20:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹni-Hádádì sì wí pé, “Èmi yóò dá àwọn ìlú tí baba mi ti gbà lọ́wọ́ baba rẹ padà, ìwọ sì le la ọ̀nà fún ara rẹ ní Dámáskù, bí baba mi ti ṣe ní Samáríà.”Áhábù sì wí pé, “Èmi yóò rán ọ lọ pẹ̀lú májẹ̀mú yìí.” Bẹ́ẹ̀ ni ó ba dá májẹ̀mú, ó sì rán an lọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 20

Wo 1 Ọba 20:34 ni o tọ