Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 20:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí o sì tún kó ogun jọ fún ara rẹ bí èyí tí ó ti sọnù; ẹṣin fún ẹṣin, kẹ̀kẹ́ fún kẹ̀kẹ́; kí a bá lè bá Ísírẹ́lì jà ní pẹ̀tẹ́lẹ̀. Nítòótọ́ àwa yóò ní agbára jù wọ́n lọ.” Ó sì gba ti wọn, ó sì ṣe bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 20

Wo 1 Ọba 20:25 ni o tọ