Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 20:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì jáde lọ ní ọ̀sán gangan, nígbà tí Bẹni-Hádádì àti àwọn ọba méjìlélọ́gbọ̀n tí ń ràn án lọ́wọ́ ń mu àmúpara nínú àgọ́.

Ka pipe ipin 1 Ọba 20

Wo 1 Ọba 20:16 ni o tọ