Nígbà náà ni ọba pàṣẹ fún Bénáyà ọmọ Jéhóíádà, ó sì jáde lọ, ó sì kọlu Ṣíméhì, ó sì pa á.Ìjọba náà sì wá fi ìdí múlẹ̀ ní ọwọ́ Sólómónì.