Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba pe Síméì lẹ́jọ́, ó wí fún un pé, “Ǹjẹ́ èmi kò ti mú ọ búra ní ti Olúwa, èmi sì ti kìlọ̀ fún ọ pé, ‘Ní ọjọ́ tí ìwọ bá kúrò láti lọ sí ibikíbi, kí o mọ̀ dájú pé ìwọ yóò kú’? Nígbà náà ni ìwọ sì sọ fún mi pé, ‘Ohun tí ìwọ sọ dára. Èmi yóò ṣe ìgbọ́ràn.’

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:42 ni o tọ