Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:40 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fún ìdí èyí, ó sì di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀ ní gàárì, ó sì lọ sọ́dọ̀ Ákíṣì ní Gátì láti wá àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀. Bẹ́ẹ̀ ni Síméì sì lọ, ó sì mú àwọn ọmọ ọ̀dọ̀ rẹ̀ padà bọ̀ láti Gátì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:40 ni o tọ