Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ọba sì dá ìyá rẹ̀ lóhùn pé, “Èéṣe tí ìwọ fi béèrè Ábíságì ará Súnémù fún Àdóníjà! Ìwọ ìbá sì béèrè ìjọba fún un pẹ̀lú nítorí ẹ̀gbọ́n mi ni í ṣe, fún òun pàápàá àti fún Ábíátarì àlùfáà àti fun Jóábù ọmọ Sérúíà!”

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:22 ni o tọ