Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni ó sì tẹ̀ṣíwájú pé, “Mo bẹ̀ ọ́, jọ̀wọ́ sọ fún Sólómónì ọba (Òun kì yóò kọ̀ fún ọ́) kí ó fún mi ní Ábíságì ará Súnémù ní aya.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:17 ni o tọ