Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 19:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nígbà tí òun tìkárarẹ̀ sì lọ ní ìrìn ojọ́ kan sí ihà, ó sì wá sí ibi igi ọwọ̀ kan, ó sì jókòó lábẹ́ rẹ̀, ó sì gbàdúrà kí òun bá le kú, wí pé, “Mo ti ní tó, Olúwa, gba ẹ̀mí mi kúrò; nítorí èmi kò sàn ju àwọn baba mi lọ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:4 ni o tọ