Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Ọbadíà sì ti ń rìn lọ, Èlíjà sì pàdé rẹ̀. Ọbadíà sì mọ̀ ọ́, ó dojú bolẹ̀, ó sì wí pé, “Ǹjẹ́ ìwọ ni ní tòótọ́, Èlíjà, Olúwa mi?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:7 ni o tọ