Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà keje, ìránṣẹ́ náà sì wí pé, “Àwọ̀sánmọ̀ kékeré kan dìde láti inú òkun, gẹ́gẹ́ bí ọwọ́ ènìyàn.”Èlíjà sì wí pé, “Lọ, kí o sọ fún Áhábù pé, ‘Di kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ, kí o sì sọ̀kalẹ̀ lọ, kí òjò ó má ba à dá ọ dúró.’ ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:44 ni o tọ