Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Áhábù gòkè lọ láti jẹ àti láti mu. Ṣùgbọ́n Èlíjà gun orí òkè Kámẹ́lì lọ ó sì tẹríba, ó sì fi ojú rẹ̀ sí agbede-méjì eékún rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:42 ni o tọ