Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fún wa ní ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù méjì. Jẹ́ kí wọn kí ó sì yan ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù kan fún ara wọn, kí wọn kí ó sì ké e sí wẹ́wẹ́, kí wọn kí ó sì tò ó sí orí igi, kí wọn kí ó má ṣe fi iná sí i. Èmi yóò sì tún ẹgbọ̀rọ̀ akọ màlúù kejì ṣe, èmi yóò sì tò ó sórí igi, èmi kì yóò sì fi iná sí i.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:23 ni o tọ