Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà sì dá a lóhùn pé, “Èmi kò yọ Ísírẹ́lì lẹ́nu, bí kò ṣe ìwọ àti ilé bàbá rẹ. Ẹ ti kọ òfin Olúwa sílẹ̀, ẹ sì ń tọ Báálímù lẹ́yìn.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:18 ni o tọ