Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 18:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo mọ̀ dájú pé bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti ń bẹ, kò sí orílẹ̀ èdè tàbí ìjọba kan tí olúwa mi kò ti rán ènìyàn lọ láti wò ọ́. Àti nígbà tí orílẹ̀ èdè tàbí ìjọba kan bá wí pé o kò sí, òun a sì mú kí wọ́n búra wí pé wọn kò rí ọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 18

Wo 1 Ọba 18:10 ni o tọ