Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí báyìí ni Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: ‘Ìkòkò ìyẹ̀fun náà kì yóò ṣófo, bẹ́ẹ̀ ni kólòbó òróró náà kì yóò gbẹ, títí di ọjọ́ tí Olúwa yóò rọ òjò sí orí ilẹ̀.’ ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:14 ni o tọ