Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin opó náà sì dá a lóhùn wí pé, “Bí Olúwa Ọlọ́run rẹ ti wà, èmi kò ní àkàrà: bí kò ṣe ìkúnwọ́ ìyẹ̀fun nínú ìkòkò àti òróró díẹ̀ nínú kólòbó. Èmi ń ṣa igi díẹ̀ jọ láti kó lọ ilé, kí èmi kí ó sì pèsè rẹ̀ fún mi àti fún ọmọ mi, kí àwa lè jẹ ẹ́: kí a sì kú.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:12 ni o tọ