Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíjà ará Tíṣíbì, láti Tíṣíbì ní Gílíádì wí fún Áhábù pé, “Bí Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì ti wà, ẹni tí èmi ń sìn, kì yóò sí ìrì tàbí òjò ní ọdún díẹ̀ tí ń bọ̀ bí kò ṣe nípa ọ̀rọ̀ mi.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:1 ni o tọ