Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 16:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìgbà ayé Áhábù, Híélì ará Bétélì kọ́ Jẹ́ríkò. Ó fi ìpìlẹ̀ rẹ̀ lé ilẹ̀ ní Ábírámù, àkọ́bí rẹ, ó sì gbé àwọn ilẹ̀kùn ibodè rẹ̀ kọ́ ní Ṣégúdù àbíkẹ́yìn rẹ̀, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ Olúwa tí ó ti ipa Jóṣúà ọmọ Núnì sọ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 16

Wo 1 Ọba 16:34 ni o tọ