Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 16:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó rìn ní gbogbo ọ̀nà Jéróbóámù ọmọ Nébátì àti nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èyí tí ó ti mú Ísírẹ́lì ṣẹ̀, láti fi ohun asán wọn mú Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì bínú.

Ka pipe ipin 1 Ọba 16

Wo 1 Ọba 16:26 ni o tọ