Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 15:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì mú Máákà ìyá ìyá rẹ̀ kúrò láti máa ṣe ayaba, nítorí tí ó yá ère kan fún òrìṣà rẹ̀. Áṣà sì ké ère náà lulẹ̀, ó sì dáná sun ún níbi odò Kídírónì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 15

Wo 1 Ọba 15:13 ni o tọ