Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 14:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mú ìṣù àkàrà mẹ́wàá pẹ̀lú rẹ̀, àti àkàrà wẹ́wẹ́ àti ìgò oyin, kí o sì lọ sí ọ̀dọ̀ rẹ̀. Òun yóò sì ṣọ fún ọ ohun tí yóò ṣẹlẹ̀ sí ọmọkùnrin náà.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 14

Wo 1 Ọba 14:3 ni o tọ