Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 14:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo Ísírẹ́lì yóò sì ṣọ̀fọ̀ fún un, wọn yóò sì sin ín. Òun nìkan ni a ó sì sin nínú ẹni tí ń ṣe ti Jéróbóámù, nítorí lọ́dọ̀ rẹ̀ nìkan ni a ti rí ohun rere díẹ̀ sípa Olúwa Ọlọ́run Ísírẹ́lì, ní ilé Jéróbóámù.

Ka pipe ipin 1 Ọba 14

Wo 1 Ọba 14:13 ni o tọ