Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 13:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wòlíì àgbà náà sì wí fún un pé, “Wòlíì ni èmi náà pẹ̀lú, gẹ́gẹ́ bí ìwọ. Ańgẹ́lì sì sọ fún mi nípa ọ̀rọ̀ Olúwa pé: ‘Mú un padà wá sí ilé rẹ, kí ó lè jẹ oúnjẹ àti kí ó lè mu omi.’ ” (Ṣùgbọ́n ó purọ́ fún un ni.)

Ka pipe ipin 1 Ọba 13

Wo 1 Ọba 13:18 ni o tọ