Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Sólómónì ṣe búburú níwájú Olúwa; kò sì tọ Olúwa lẹ́yìn ní pípé, bí Dáfídì bàbá rẹ̀ ti ṣe.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:6 ni o tọ