Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 11:33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ṣe èyí nítorí tí wọ́n ti kọ̀ mí sílẹ̀, wọ́n sì ti sin Ásítórétì òrìṣà àwọn ará Sídónì, Kémósì òrìṣà àwọn ará Móábù, àti Mííkámù òrìṣà àwọn ọmọ Ámónì, wọn kò sì rìn ní ọ̀nà mi, tàbí ṣe èyí tí ó dára lójú mi, tàbí pa àṣẹ àti òfin mi mọ́ bí Dáfídì bàbá Sólómónì ti ṣe.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:33 ni o tọ