Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 11:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéróbóámù jẹ́ ọkùnrin alágbára, nígbà tí Sólómónì sì rí bí ọ̀dọ́mọkùnrin náà ti ṣe iṣẹ́ rẹ̀ dáradára, ó fi í ṣe olórí iṣẹ́ ìrú ilé Jóṣẹ́fù.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:28 ni o tọ