Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ó ti kìlọ̀ fún Sólómónì kí ó má ṣe tọ àwọn Ọlọ́run mìíràn lẹ́yìn, ṣùgbọ́n Sólómónì kò pa àṣẹ Olúwa mọ́.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:10 ni o tọ