Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 11:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ọba fẹ́ ọ̀pọ̀ àjèjì obìnrin yàtọ̀ sí ọmọbìnrin Fáráò, àwọn ọmọbìnrin Móábù, àti ti Ámónì, ti Édómù, ti Sídónì àti ti àwọn ọmọ Hítì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 11

Wo 1 Ọba 11:1 ni o tọ