Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé nǹkan yìí ni Olúwa mi ọba ti ṣe láìjẹ́ kí àwọn ìránṣẹ́ rẹ mọ ẹni tí yóò jókòó lórí ìtẹ́ Olúwa mi ọba lẹ́yìn rẹ?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:27 ni o tọ