Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì ti fi ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ màlúù, àti ẹran tí ó ní ọ̀rá, àti àgùntàn rúbọ, ó sì pe gbogbo àwọn ọmọ ọba, àti Ábíátarì àlùfáà àti Jóábù balógun, ṣùgbọ́n kò sì pe Sólómónì ìránṣẹ́ rẹ.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:19 ni o tọ