Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ sọ́dọ̀ Dáfídì ọba, kí o sì wí fún un pé, ‘Olúwa mi ọba, ǹjẹ́ ìwọ kò búra fún ìránṣẹ́ rẹ pé, “Dájúdájú Sólómónì ọmọ rẹ ni yóò Jọba lẹ́yìn mi, yóò sì jókòó lórí ìtẹ́ mi?” Èéṣe nígbà náà tí Àdóníjà fi jọba?’

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:13 ni o tọ