Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Dáfídì ọba di arúgbó, ọjọ́ rẹ̀ sì pọ̀, ara rẹ̀ kò le è móoru bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé wọ́n da ọ̀pọ̀lọpọ̀ aṣọ bò ó.

Ka pipe ipin 1 Ọba 1

Wo 1 Ọba 1:1 ni o tọ