Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 9:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo Ísírẹ́lì ni a kọ lẹ́sẹsẹ nínú ìtàn ìdílé láti ọ̀dọ̀ àwọn baba ńlá nínú ìwé àwọn ọba Ísírẹ́lì.Àwọn ènìyàn Júdà ni a kó ní ìgbẹ̀kùn lọ sí Bábílónì nítorí àìsòótọ́ wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 9

Wo 1 Kíróníkà 9:1 ni o tọ