Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 8:38 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áṣélì ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:Áṣíríkámù, Bókérù, Íṣímáélì, Ṣéáríà, Ọbádáyà àti Hánánì. Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Áṣélì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8

Wo 1 Kíróníkà 8:38 ni o tọ