Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 8:13-23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Pẹ̀lú Béríà àti Ṣémà, tí wọ́n jẹ́ olórí àwọn ìdílé ti àwọn tí ó ń gbé ní Áíjálónì àti àwọn tí ó lé àwọn olùgbé Gátì kúrò.

14. Áhíò, Ṣásákì Jérémílò,

15. Ṣébádíà, Árádì, Édérì

16. Míkáélì Íṣífà àti Jóhà jẹ́ àwọn ọmọ Béríà.

17. Ṣébàdíáhì, Mésúlámù Hésékì, Hébérì

18. Íṣíméráì, Íṣílíáhì àti Jóbábì jẹ́ àwọn ọmọ Élípálì.

19. Jákímì, Ṣíkírì, Ṣábídì,

20. Élíénáì Ṣílétaì Élíélì,

21. Ádáyà, Béráíáhì àti Ṣímírátì jẹ́ àwọn ọmọ, Ṣíméhì.

22. Íṣípánì Ébérì, Élíélì,

23. Ábídónì, Ṣíkírì, Hánánì,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8