Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 8:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Bẹ́ńjámínì jẹ́ bàbá Bélà àkọ́bí Rẹ̀,Áṣíbélì ọmọkùnrin ni ẹ̀ẹ̀kejì, Áhárá ẹ̀ẹ̀kẹ́ta,

2. Nóhà ẹ̀ẹ̀kẹrin àti Ráfà ẹ̀ẹ̀karùnún.

3. Àwọn ọmọ Bélà jẹ́:Ádárì, Gérà, Ábíhúdì,

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 8