Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 5:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ̀nyí sì ni àwọn olórí ilé àwọn baba wọn. Éférì, Ísì, Élíélì, Ásíríélì, Jérémáíà, Hódáfíà àti Jáhídíélì àwọn alágbára akọni ọkùnrin, ọkùnrin olókìkí, àti olórí ilé àwọn baba wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 5

Wo 1 Kíróníkà 5:24 ni o tọ