Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 3:22-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

22. Àwọn ọmọ Ṣékáníà:Ṣémáíà àti àwọn ọmọ Rẹ̀:Hátúsì, Ígéálì, Báríà, Néáríà àti Ṣáfátì, mẹ́fà ni gbogbo wọn.

23. Àwọn ọmọ Néáríà:Élíóéníà; Hísíkíà àti Ásírí kámù, mẹ́ta ni gbogbo wọn.

24. Àwọn ọmọ Élíóéníà:Hódáíà, Élíásíbù, Pétéláéà, Ákúbù, Jóhánánì, Déláyà àti Ánánì, méje sì ni gbogbo wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3