Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 3:2-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Ẹ̀kẹta sì ni Ábúsálómù ọmọ Mákà ọmọbìnrin ti Táímáì ọba Gésúrì;ẹ̀kẹrin sì ni Àdóníjà ọmọ Hágítì;

3. Ẹ̀kárùnún ni Ṣéfátíyà ọmọ Ábítalì;àti ẹ̀kẹfà, Ítíréàmù, láti ọ̀dọ̀ ìyàwó Rẹ̀ Égílà.

4. Ẹ̀kẹfà ni a bí fún Dáfídì ni Hébúrónì, níbi tí ó ti jẹ ọba fún ọdún méje àti oṣù mẹ́fà.Dáfídì sì jẹ ọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mẹ́talélọ́gbọ̀n (33).

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3