Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 3:16-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

16. Àwọn ìran ọmọ Jéhóíákímù:Jékóníà ọmọ Rẹ̀,àti Ṣedékíà.

17. Àwọn ọmọ Jéhóíákímù tí a mú ní ìgbékùn:Ṣálátíélì ọmọ Rẹ̀ ọkùnrin,

18. Málíkírámù, Pédáíyà, Ṣénásárì, Jékámíà, Hósámà àti Nédábíà.

19. Àwọn ọmọ Pédáíyà:Ṣérúbábélì àti Ṣíméhì.Àwọn ọmọ Ṣérúbábélì:Mésúlámù àti Hánáníyà,Ṣélómítì ni arábìnrin wọn.

20. Àwọn márùnún mìíràn sì tún wà:Hásúbà, Óhéhì, Bérékíà, Hasádíà àti Jusabi-Hésédì.

21. Àwọn ọmọ Hánáníyà:Pélátíà àti Jeṣáíà, àti àwọn ọmọ Réfáíà, ti Árínánì, ti Ọbadíà àti ti ṣékáníà.

22. Àwọn ọmọ Ṣékáníà:Ṣémáíà àti àwọn ọmọ Rẹ̀:Hátúsì, Ígéálì, Báríà, Néáríà àti Ṣáfátì, mẹ́fà ni gbogbo wọn.

23. Àwọn ọmọ Néáríà:Élíóéníà; Hísíkíà àti Ásírí kámù, mẹ́ta ni gbogbo wọn.

24. Àwọn ọmọ Élíóéníà:Hódáíà, Élíásíbù, Pétéláéà, Ákúbù, Jóhánánì, Déláyà àti Ánánì, méje sì ni gbogbo wọn.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3