Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 3:13-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Áhásì ọmọ Rẹ̀,Hesekíáyà ọmọ Rẹ̀,Mánásè ọmọ Rẹ̀,

14. Ámónì ọmọ Rẹ̀,Jósíà ọmọ Rẹ̀.

15. Àwọn ọmọ Jósíà:Àkọ́bí ọmọ Rẹ̀ ni Jóhánánì,èkejì ọmọ Rẹ̀ ni Jéhóíákímù,ẹ̀kẹta ọmọ Rẹ̀ ni Ṣédékíà,ẹ̀kẹ́rin ọmọ Rẹ̀ ni Ṣálúmù.

16. Àwọn ìran ọmọ Jéhóíákímù:Jékóníà ọmọ Rẹ̀,àti Ṣedékíà.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3