Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 3:11-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

11. Jéhórámù ọmọ Rẹ̀,Áhásáyà ọmọ Rẹ̀,Jóásì ọmọ Rẹ̀,

12. Ámásáyà ọmọ Rẹ̀,Ásáríyà ọmọ Rẹ̀,Jótamù ọmọ Rẹ̀,

13. Áhásì ọmọ Rẹ̀,Hesekíáyà ọmọ Rẹ̀,Mánásè ọmọ Rẹ̀,

14. Ámónì ọmọ Rẹ̀,Jósíà ọmọ Rẹ̀.

15. Àwọn ọmọ Jósíà:Àkọ́bí ọmọ Rẹ̀ ni Jóhánánì,èkejì ọmọ Rẹ̀ ni Jéhóíákímù,ẹ̀kẹta ọmọ Rẹ̀ ni Ṣédékíà,ẹ̀kẹ́rin ọmọ Rẹ̀ ni Ṣálúmù.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 3