Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 29:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa gbé Solómónì ga púpọ̀ ní ojú gbogbo Ísírẹ́lì, ó sì kẹ́ ẹ ní ìkẹ́ ọlá ńlá, ní irú èyí tí a kò kẹ́ ọba kankan ṣáájú Rẹ̀ tí ó jẹ lórí Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 29

Wo 1 Kíróníkà 29:25 ni o tọ