Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àti ìwọ, ọmọ mi Sólómónì, rántí Ọlọ́run baba à rẹ, kí o sì sìn-ín pẹ̀lú tọkàntọkàn pẹ̀lú ìfọkànsí pẹ̀lú ọkàn tí ó pé, nítorí Olúwa ṣàwárí gbogbo ọkàn ó sì mọ gbogbo èrò. Tí ìwọ bá wá a, ìwọ yóò rí i; ṣùgbọ́n tí ìwọ bá kọ̀ọ́ sílẹ̀, òun yóò kọ̀ọ́ títí láé.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:9 ni o tọ