Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìpín àwọn àlùfáà àti àwọn ará Léfì ti ṣetan fún gbogbo iṣẹ́ ilé Olúwa. Gbogbo ọkùnrin tí ó ní ìfẹ́ sí i tí ó sì ní òye oríṣìíríṣìí iṣẹ́. Yóò ràn ọ́ lọ́wọ́ nínú iṣẹ́ náà. Àwọn ìjòyè àti gbogbo àwọn ènìyàn yóò gbọ́ràn sí gbogbo àṣẹ rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:21 ni o tọ