Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Dáfídì dìde dúró ní ẹṣẹ̀ Rẹ̀, o sì wí pé Fetísílẹ̀ sí mi, ẹyin ará mi àti ẹ̀yin ènìyàn mi. Èmi ní o ni ọkàn mi láti kọ́ ilé gẹ́gẹ́ bí ibi ìsinmi fún àpótí ẹ̀rí májẹ̀mú tí Olúwa fún àpótí ìtìsẹ̀ Ọlọ́run wa, èmi sì gbèrò láti kọ́ ọ.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:2 ni o tọ