Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Kíróníkà 28:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó fún un ní àwọn ètò gbogbo èyí tí ẹ̀mí ti fi sí ọkàn Rẹ̀ fún ti ààfin ilé Olúwa àti gbogbo yàrá tí ó yíká fún ìṣúra ilé Ọlọ́run àti fún ìṣúra fún ohun yíyà sọ́tọ̀.

Ka pipe ipin 1 Kíróníkà 28

Wo 1 Kíróníkà 28:12 ni o tọ